TỌ́MÌ ÀTI IRÚGBÌN KÉKERÉ (Tommy and the Little Seed) (Yoruba version)
ISBN: 9781961178120
$12.98
1961178125
Ní òye àyọ̀ tó wà nínú ìṣẹ̀dá pẹ̀lú 'TỌ́MÌ ÀTI IRÚGBÌN KÉKERÉ'. Ìtàn aládùn yìí ń pe àwọn òǹkàwé lọmọdé, bẹ̀rẹ̀ láti ọmọ òòjọ́ sí ọmọ ọdún márùn-ún sí ìgbé ayé Tọ́mì, tí ó jẹ́ aláwáfín ọmọdé-kùnrin, níbi tí ó ti ṣe àwárí idán tí ó sodo sínú gbígbin irúgbìn kékeré àti bí ó ṣe fojú rí ìdàgbàsókè ńlá tí ó dé bá irúgbìn náà nípa yíyírapadà láti di òdòdó alárinrin. Ìwé yìí ṣe àfihàn tí ó pé nípa àwọn ohun àrà tí ó wà nínú iṣẹ̀dá fún àwọn ọmọdé pẹ̀lú àwọn àwòrán aláràǹbarà.